Kronika Kinni 19:19 BM

19 Nígbà tí àwọn iranṣẹ Hadadeseri rí i pé Israẹli ti ṣẹgun àwọn, wọ́n bẹ Dafidi, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí sìn ín. Nítorí náà, àwọn ará Siria kò wá ran àwọn ará Amoni lọ́wọ́ mọ́.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 19

Wo Kronika Kinni 19:19 ni o tọ