Kronika Kinni 2:3 BM

3 Juda bí ọmọ marun-un. Batiṣua, aya rẹ̀, ará Kenaani, bí ọmọ mẹta fún un: Eri, Onani ati Ṣela. Eri, àkọ́bí Juda, jẹ́ eniyan burúkú lójú OLUWA, OLUWA bá pa á.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 2

Wo Kronika Kinni 2:3 ni o tọ