Kronika Kinni 2:42 BM

42 Àwọn ọmọ Kalebu, arakunrin Jerameeli, nìwọ̀nyí: Mareṣa, baba Sifi ni àkọ́bí rẹ̀. Lẹ́yìn náà, ó bí Heburoni.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 2

Wo Kronika Kinni 2:42 ni o tọ