49 Maaka yìí kan náà ni ó bí Ṣaafu, baba Madimana, tí ó tẹ ìlú Madimana dó, ati Ṣefa, baba Makibena ati Gibea, àwọn ni wọ́n tẹ ìlú Makibena ati ìlú Gibea dó.Kalebu tún bí ọmọbinrin kan tí ń jẹ́ Akisa.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 2
Wo Kronika Kinni 2:49 ni o tọ