8 Ìran òmìrán, ará Gati ni àwọn mẹtẹẹta; Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ ni ó sì pa wọ́n.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 20
Wo Kronika Kinni 20:8 ni o tọ