Kronika Kinni 21:14 BM

14 Nítorí náà, Ọlọrun rán àjàkálẹ̀ àrùn sórí ilẹ̀ Israẹli, àwọn tí wọ́n kú sì jẹ́ ẹgbaa marundinlogoji (70,000) eniyan.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 21

Wo Kronika Kinni 21:14 ni o tọ