18 Angẹli OLUWA bá pàṣẹ fún Gadi pé kí ó lọ sọ fún Dafidi pé kí ó lọ tẹ́ pẹpẹ kan fún OLUWA ní ibi ìpakà Onani ará Jebusi.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 21
Wo Kronika Kinni 21:18 ni o tọ