12 Kí OLUWA fún ọ ní ọgbọ́n ati làákàyè kí o lè máa pa òfin OLUWA Ọlọrun rẹ mọ́ nígbà tí ó bá fi ọ́ jọba lórí Israẹli.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 22
Wo Kronika Kinni 22:12 ni o tọ