Kronika Kinni 22:8 BM

8 ṣugbọn OLUWA sọ fún mi pé mo ti ta ọpọlọpọ ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀, mo sì ti ja ọpọlọpọ ogun; nítorí ọpọlọpọ ìtàjẹ̀sílẹ̀ náà, òun kò ní gbà pé kí n kọ́ tẹmpili òun.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 22

Wo Kronika Kinni 22:8 ni o tọ