Kronika Kinni 23:17 BM

17 Elieseri bí ọmọkunrin kan tí ń jẹ́ Rehabaya, olórí ìdílé rẹ̀, kò sì bí ọmọ mìíràn mọ́, ṣugbọn àwọn ọmọ Rehabaya pọ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 23

Wo Kronika Kinni 23:17 ni o tọ