Kronika Kinni 23:32 BM

32 Bẹ́ẹ̀ ni wọn yóo ṣe máa bojútó Àgọ́ Àjọ ati ibi mímọ́, tí wọn yóo sì máa ran àwọn ọmọ Aaroni, àwọn arakunrin wọn lọ́wọ́, níbi iṣẹ́ ìsìn ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 23

Wo Kronika Kinni 23:32 ni o tọ