Kronika Kinni 25:9 BM

9 Gègé kinni tí wọ́n ṣẹ́ fún ìdílé Asafu mú Josẹfu; ekeji mú Gedalaya, òun ati àwọn arakunrin rẹ̀ ati àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin jẹ́ mejila.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 25

Wo Kronika Kinni 25:9 ni o tọ