Kronika Kinni 26:15 BM

15 Obedi Edomu ni gègé mú fún ẹnu ọ̀nà ti ìhà gúsù; àwọn ọmọ rẹ̀ ni a sì yàn láti máa ṣọ́ ilé ìṣúra.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 26

Wo Kronika Kinni 26:15 ni o tọ