Kronika Kinni 26:2 BM

2 Meṣelemaya bí ọmọ meje, orúkọ wọn nìyí gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ orí wọn, Sakaraya ni àkọ́bí, lẹ́yìn náà Jediaeli, Sebadaya, ati Jatinieli;

Ka pipe ipin Kronika Kinni 26

Wo Kronika Kinni 26:2 ni o tọ