Kronika Kinni 26:24 BM

24 Ṣebueli, ọmọ Geriṣomu, láti inú ìran Mose, ni olórí àwọn tí ń bojútó ibi ìṣúra.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 26

Wo Kronika Kinni 26:24 ni o tọ