29 Ninu ìdílé Iṣari, Kenanaya ati àwọn ọmọ rẹ̀ ni wọ́n yàn ní alákòóso ati onídàájọ́ fún àwọn ọmọ Israẹli.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 26
Wo Kronika Kinni 26:29 ni o tọ