Kronika Kinni 27:13 BM

13 Balogun tí ó wà fún oṣù kẹwaa ni Maharai, ará Netofa láti inú ìran Serahi; iye àwọn tí wọ́n wà ninu ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaaji (24,000).

Ka pipe ipin Kronika Kinni 27

Wo Kronika Kinni 27:13 ni o tọ