Kronika Kinni 27:29 BM

29 Ṣitirai, ará Ṣaroni, ni ó wà fún àwọn agbo mààlúù tí wọ́n wà ní Ṣaroni. Ṣafati, ọmọ Adila, ni ó wà fún àwọn agbo mààlúù tí wọ́n wà ní àwọn àfonífojì.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 27

Wo Kronika Kinni 27:29 ni o tọ