Kronika Kinni 27:6 BM

6 Bẹnaya yìí jẹ́ ọ̀kan ninu àwọn ọgbọ̀n akọni jagunjagun, òun sì ni olórí wọn. Amisabadi ọmọ rẹ̀ ni ó ń ṣe àkóso ìpín rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 27

Wo Kronika Kinni 27:6 ni o tọ