Kronika Kinni 27:8 BM

8 Balogun tí ó wà fún oṣù karun-un ni Ṣamuhutu, láti inú ìran Iṣari; iye àwọn tí wọ́n wà ninu ìpín rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaaji (24,000).

Ka pipe ipin Kronika Kinni 27

Wo Kronika Kinni 27:8 ni o tọ