Kronika Kinni 29:16 BM

16 OLUWA, Ọlọrun wa, tìrẹ ni gbogbo ohun tí a mú wá, láti fi kọ́ ilé fún orúkọ mímọ́ rẹ, ọ̀dọ̀ rẹ ni wọ́n sì ti wá.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 29

Wo Kronika Kinni 29:16 ni o tọ