Kronika Kinni 29:18 BM

18 OLUWA Ọlọrun àwọn baba wa: Abrahamu, Isaaki ati Israẹli, jẹ́ kí irú ẹ̀mí yìí túbọ̀ máa wà ninu àwọn eniyan rẹ títí lae, kí o sì jẹ́ kí ọkàn wọn máa fà sí ọ̀dọ̀ rẹ.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 29

Wo Kronika Kinni 29:18 ni o tọ