Kronika Kinni 29:25 BM

25 OLUWA gbé Solomoni ga lójú gbogbo àwọn ọmọ Israẹli, ó sì fún un ní ọlá ju gbogbo àwọn ọba tí wọ́n ti jẹ ṣáájú rẹ̀ ní Israẹli.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 29

Wo Kronika Kinni 29:25 ni o tọ