Kronika Kinni 29:8 BM

8 Gbogbo àwọn tí wọ́n ní òkúta olówó iyebíye ni wọ́n mú wọn wá tí wọ́n fi wọ́n sí ibi ìṣúra ilé OLUWA, tí ó wà lábẹ́ àbojútó Jehieli ará Geriṣoni.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 29

Wo Kronika Kinni 29:8 ni o tọ