Kronika Kinni 3:22 BM

22 Ṣekanaya ní ọmọ kan, tí ń jẹ́ Ṣemaaya. Ṣemaaya bí ọmọ marun-un: Hatuṣi, Igali, Baraya, Nearaya ati Ṣafati.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 3

Wo Kronika Kinni 3:22 ni o tọ