Kronika Kinni 4:14 BM

14 Meonotai ni baba Ofira.Seraaya sì ni baba Joabu, baba àwọn ará Geharaṣimu, ìlú àwọn oníṣọ̀nà. Àwọn ni wọ́n tẹ gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ àwọn oníṣẹ́ ọwọ́ dó.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 4

Wo Kronika Kinni 4:14 ni o tọ