Kronika Kinni 4:2 BM

2 Ṣobali ni ó bí Reaaya. Reaaya sì bí Jahati. Jahati ni baba Ahumai ati Lahadi. Àwọn ni ìdílé àwọn tí ń gbé Sora.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 4

Wo Kronika Kinni 4:2 ni o tọ