Kronika Kinni 4:39 BM

39 Wọ́n rìn títí dé ẹnubodè Gedori, ní apá ìlà oòrùn àfonífojì, láti wá koríko fún àwọn ẹran ọ̀sìn wọn.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 4

Wo Kronika Kinni 4:39 ni o tọ