Kronika Kinni 4:42 BM

42 Ẹẹdẹgbẹta (500) ninu àwọn eniyan Simeoni ló lọ sí òkè Seiri; àwọn olórí wọn ni: Pelataya, Nearaya, Refaaya, ati Usieli, lára àwọn ọmọ Iṣi.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 4

Wo Kronika Kinni 4:42 ni o tọ