Kronika Kinni 4:9 BM

9 Ọkunrin kan, tí à ń pè ní Jabesi, jẹ́ eniyan pataki ju àwọn arakunrin rẹ̀ lọ. Ìyá rẹ̀ sọ ọ́ ní orúkọ yìí nítorí ìrora pupọ tí ó ní nígbà tí ó bí i.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 4

Wo Kronika Kinni 4:9 ni o tọ