Kronika Kinni 5:17 BM

17 A kọ àkọsílẹ̀ wọn ní àkókò Jotamu, ọba Juda, ati ní àkókò Jeroboamu ọba Israẹli.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 5

Wo Kronika Kinni 5:17 ni o tọ