Kronika Kinni 5:2 BM

2 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀yà Juda di ẹ̀yà tí ó lágbára ju gbogbo ẹ̀yà yòókù lọ, tí wọ́n sì ń jọba lórí wọn, sibẹsibẹ ipò àkọ́bí jẹ́ ti àwọn ọmọ Josẹfu).

Ka pipe ipin Kronika Kinni 5

Wo Kronika Kinni 5:2 ni o tọ