Kronika Kinni 6:44 BM

44 Etani arakunrin wọn láti inú ìdílé Merari ni olórí àwọn ẹgbẹ́ akọrin tí ń dúró ní apá òsì rẹ̀. Ìran Etani títí lọ kan Lefi nìyí: ọmọ Kiṣi ni Etani, ọmọ Abidi, ọmọ Maluki;

Ka pipe ipin Kronika Kinni 6

Wo Kronika Kinni 6:44 ni o tọ