Kronika Kinni 6:65 BM

65 Wọ́n tún ṣẹ́ gègé láti fún wọn ní àwọn ìlú ńláńlá tí a dárúkọ wọnyi lára ìlú àwọn ẹ̀yà Juda, Simeoni ati ti Bẹnjamini.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 6

Wo Kronika Kinni 6:65 ni o tọ