Kronika Kinni 6:71 BM

71 Ninu ilẹ̀ ìdajì ẹ̀yà Manase tí ó wà ní ìhà ìlà oòrùn, wọ́n fún àwọn ọmọ Geriṣoni ní ìlú wọnyi, pẹlu àwọn pápá oko tí ó yí wọn ká: Golani ní ilẹ̀ Baṣani, ati Aṣitarotu.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 6

Wo Kronika Kinni 6:71 ni o tọ