Kronika Kinni 7:17 BM

17 Ulamu sì bí Bedani. Àwọn ni ọmọ Gileadi, ọmọ Makiri, ọmọ Manase.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 7

Wo Kronika Kinni 7:17 ni o tọ