Kronika Kinni 7:3 BM

3 Usi ni ó bí Isiraya. Isiraya sì bí ọmọ mẹrin: Mikaeli, Ọbadaya, Joẹli, ati Iṣaya; wọ́n di marun-un, àwọn maraarun ni wọ́n sì jẹ́ ìjòyè.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 7

Wo Kronika Kinni 7:3 ni o tọ