Kronika Kinni 7:5 BM

5 Gbogbo àwọn akikanju jagunjagun tí a kọ orúkọ wọn sílẹ̀ ninu àwọn ìbátan wọn ninu ẹ̀yà Isakari jẹ́ ẹgbaa mẹtalelogoji ó lé ẹgbẹrun (87,000).

Ka pipe ipin Kronika Kinni 7

Wo Kronika Kinni 7:5 ni o tọ