Kronika Kinni 7:9 BM

9 Àkọsílẹ̀ ìran wọn ní ìdílé, àwọn baálé baálé ní ilé baba wọn, tí wọ́n jẹ́ akọni jagunjagun, gbogbo wọn jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ati igba (20,200).

Ka pipe ipin Kronika Kinni 7

Wo Kronika Kinni 7:9 ni o tọ