Kronika Kinni 8:12 BM

12 Elipaali bí ọmọkunrin mẹta: Eberi, Miṣamu ati Ṣemedi. Ṣemedi yìí ni ó kọ́ àwọn ìlú Ono, Lodi, ati gbogbo àwọn ìletò tí ó yí wọn ká.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 8

Wo Kronika Kinni 8:12 ni o tọ