Kronika Kinni 9:23 BM

23 Nítorí náà, àwọn ati àwọn ọmọ wọn ni wọ́n ń ṣe alabojuto ẹnu ọ̀nà ilé OLUWA, àwọn ni wọ́n fi ṣe olùṣọ́ Àgọ́ Àjọ.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 9

Wo Kronika Kinni 9:23 ni o tọ