Kronika Kinni 9:29 BM

29 Iṣẹ́ àwọn mìíràn ninu wọn ni láti máa tọ́jú ohun ọ̀ṣọ́ tẹmpili ati ohun èlò mímọ́, ati ìyẹ̀fun ọkà, waini, òróró, turari, ati òjíá.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 9

Wo Kronika Kinni 9:29 ni o tọ