Eks 14:28 YCE

28 Omi si pada, o si bò kẹkẹ́, ati awọn ẹlẹṣin, ati gbogbo ogun Farao ti o wọ̀ inu okun tọ̀ wọn lẹhin lọ; ọkanṣoṣo kò kù ninu wọn.

Ka pipe ipin Eks 14

Wo Eks 14:28 ni o tọ