Eks 14:29 YCE

29 Ṣugbọn awọn ọmọ Israeli rìn ni iyangbẹ ilẹ lãrin okun; omi si jẹ́ odi fun wọn li ọwọ́ ọtún, ati li ọwọ́ òsi wọn.

Ka pipe ipin Eks 14

Wo Eks 14:29 ni o tọ