Eks 19:2 YCE

2 Nwọn sá ti ṣi kuro ni Refidimu, nwọn si wá si ijù Sinai, nwọn si dó si ijù na; nibẹ̀ ni Israeli si dó si niwaju oke na.

Ka pipe ipin Eks 19

Wo Eks 19:2 ni o tọ