Eks 3:9 YCE

9 Njẹ nisisiyi, kiyesi i, igbe awọn ọmọ Israeli dé ọdọ mi; emi si ti ri pẹlu, wahala ti awọn ọba Egipti nwahala wọn.

Ka pipe ipin Eks 3

Wo Eks 3:9 ni o tọ