Eks 6:27 YCE

27 Awọn wọnyi li o bá Farao ọba Egipti sọ̀rọ lati mú awọn ọmọ Israeli jade kuro ni Egipti: wọnyi ni Mose ati Aaroni na.

Ka pipe ipin Eks 6

Wo Eks 6:27 ni o tọ