Eks 6:26 YCE

26 Wọnyi ni Aaroni on Mose na, ẹniti OLUWA sọ fun pe, Ẹ mú awọn ọmọ Israeli jade kuro ni ilẹ Egipti, gẹgẹ bi ogun wọn.

Ka pipe ipin Eks 6

Wo Eks 6:26 ni o tọ