Isa 10:7 YCE

7 Ṣugbọn on kò rò bẹ̃, bẹ̃ni ọkàn rẹ̀ kò rò bẹ̃; ṣugbọn o wà li ọkàn rẹ̀ lati parun ati lati ke orilẹ-ède kuro, ki iṣe diẹ.

Ka pipe ipin Isa 10

Wo Isa 10:7 ni o tọ