Isa 51:7 YCE

7 Gbọ́ ti emi, ẹnyin ti o mọ̀ ododo, enia ninu aiya ẹniti ofin mi mbẹ; ẹ máṣe bẹ̀ru ẹgàn awọn enia, ẹ má si ṣe foyà ẹsín wọn.

Ka pipe ipin Isa 51

Wo Isa 51:7 ni o tọ